“Bí ìlà-oòrùn ti jìnnà sí ìwọ̀-oòrùn, bẹ́ẹ̀ ni ó ti mú ẹ̀ṣẹ̀ wa jìnnà kúrò lọ́dọ̀ wa.”
Nígbà tí Ọlọ́run bá dáríjì ọ́, yóò mú ẹ̀ṣẹ̀ rẹ kúrò ní ọ̀nà jíjìn tó bẹ́ẹ̀ tí ìlà-oòrùn fi jìnnà sí ìwọ̀-oòrùn, ọ̀nà jíjìn tí kò lópin. Ohun tí ó sin, má ṣe lọ máa wá kiri nítorí pé ẹ̀bi yóò mú ọ ya wèrè. Ìtàn ni ohun tó ti kọjá. Ọjọ́ iwájú jẹ́ àṣírí. Ọjọ́ ìsinsìnyí jẹ́ ẹ̀bùn.
Gba awọn iṣẹlẹ tuntun wa pẹlu iwunilori
akoonu imeli nigbagbogbo