“Ẹ wá sọ́dọ̀ mi, gbogbo ẹ̀yin tí ń ṣe àárẹ̀ tí a sì di ẹrù wúwo lé lórí, èmi yóò sì fún yín ní ìsinmi.”
Sinmi kí o sì gbàdúrà nípa jíjọ̀wọ́ ohunkóhun tí ó ń mú ọ rẹ̀wẹ̀sì nípa ti ara, ti ọpọlọ, ti ìmọ̀lára, àti ti ẹ̀mí. Jésù ṣe bẹ́ẹ̀. Tẹ̀lé àpẹẹrẹ Rẹ̀.
Gba awọn iṣẹlẹ tuntun wa pẹlu iwunilori
akoonu imeli nigbagbogbo