“Fi ọ̀nà rẹ lé Olúwa lọ́wọ́; gbẹ́kẹ̀lé e, òun yóò sì ṣe èyí.”
Àyíká Sáàmù 37 ló pinnu ìtumọ̀ ẹsẹ Ìwé Mímọ́ yìí. Dáfídì bẹ̀rẹ̀ orin yìí nípa títẹnumọ́ pé kí a má ṣe ṣàníyàn nípa àwọn ẹni ibi.
Gba awọn iṣẹlẹ tuntun wa pẹlu iwunilori
akoonu imeli nigbagbogbo